Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn September
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 413 134.2 15.8 62.2 11.0
Aṣá Déédéé 23,987 57.8 7.3 22.1 5.4
Aṣá Olù. 8,363 49.5 4.7 15.0 3.6
Akéde 193,776 10.6 1.0 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 226,539 Àwọn Tí A Batisí: 1,122
A láyọ̀ láti ròyìn góńgó tó ju ti ìgbàkigbà rí lọ ti 226,539 akéde ní oṣù September. A tún ní góńgó tuntun nínú iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tí iye wọ́n jẹ́ 23,987. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé a ò dórí góńgó wa ti 25,000 aṣáájú ọ̀nà déédéé lóṣù September, bí a ṣe kọbi ara sí ìpè náà fún aṣáájú ọ̀nà púpọ̀ sí i wúni lórí.