Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 458 135.0 25.2 65.5 12.2
Aṣá. Déédéé 26,734 51.3 8.4 20.2 5.4
Aṣá. Olù. 22,352 43.9 6.3 13.4 3.3
Akéde 191,369 10.2 1.8 3.7 1.1
ÀRÒPỌ̀ 240,913 Àwọn tó ṣèrìbọmi: 421
Ní oṣù April, iye àwọn akéde pọ̀ ju ti ìgbàkígbà rí lọ, wọ́n jẹ́ 240,913. Iye ìwé ńlá, ìwé pẹlẹbẹ, àti ìwé ìròyìn táa fi sóde tún pọ̀ ju ti ìgbàkígbà rí lọ pẹ̀lú bẹ́ẹ̀ sì ni iye ìpadàbẹ̀wò táa ṣe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé táa darí tún pọ̀ sí i. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún ìròyìn dáadáa yìí.