Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn March
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 458 132.7 29.8 62.7 13.1
Aṣá. Déédéé 27,467 51.8 13.3 20.1 5.2
Aṣá. Olù. 16,101 44.0 10.9 14.3 3.5
Akéde 203,467 10.3 3.0 3.7 1.1
ÀRÒPỌ̀ 247,493 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 442
A láyọ̀ láti ròyìn pé iye àwa akéde tún ti pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ, iye wá jẹ́ 247,493 ní oṣù March. A ní àwọn akéde 422 láfikún sí iye tá a jẹ́ tẹ́lẹ̀ ní oṣù September. A tún ní ìbísí tó pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ láwọn àgbègbè mìíràn, irú bíi 27,467 aṣáájú ọ̀nà déédéé, 1,168,166 ìwé ìròyìn, 1,568,913 ìpadàbẹ̀wò, àti 428,612 ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún bó ṣe rọ̀jò ìbùkún sórí àwọn ìgbòkègbodò wa ní ọ̀nà àkànṣe yìí.