Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì!
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ọ̀sẹ̀ June 27, 2005, sí ọ̀sẹ̀ April 10, 2006.
Ọ̀SẸ̀ TI ORÍ ÀWỌN ÌPÍNRỌ̀ ẸSẸ TÍ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
June 27 1 1 sí 18
July 4 2 1 sí 15
11 2 16 sí 32
Aug. 1 3 27 sí 37 Dán. 1:16-21
Sept. 5 5 18 sí 25* Dán. 3:19-30
Oct. 3 7 17 sí 28 Dán. 5:24-31
Nov. 7 9 20 sí 32 Dán. 7:8
Dec. 5 11 1 sí 12 Dán. 9:1-23
Jan. 2 12 14 sí 22 Dán. 10:9-21
Feb. 6 14 16 sí 27 Dán. 11:25, 26
20 15 16 sí 25 Dán. 11:30b, 31
Mar. 6 16 18 sí 28 Dán. 11:42-45
Apr. 3 18 1 sí 12 Dán. 12:13
Ẹ jíròrò àfikún àlàyé nígbà tẹ́ ẹ bá dé ibi ìpínrọ̀ tàbí ìbéèrè èyíkéyìí tá a ti tọ́ka sí irú àlàyé bẹ́ẹ̀. Bí àpẹẹrẹ, bẹ́ ẹ bá dé orí 2, ìpínrọ̀ 25, ìbéèrè (d), ẹ jíròrò àpótí náà “Ọ̀ràn Èdè.” (Àpótí yìí wà lójú ìwé 26.) Ẹ jíròrò àwọn àtẹ àti àwòrán tó wà nínú ìwé náà nígbà tẹ́ ẹ bá kẹ́kọ̀ọ́ débi tí wọ́n wà. Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti ka ìpínrọ̀ tó yẹ kẹ́ ẹ kà lọ́sẹ̀ kan tán, bí àkókò bá wà, ẹ jíròrò “ẹsẹ tí ìkẹ́kọ̀ọ́ dá lé” nínú ìwé Dáníẹ́lì, níbi táwọn ìpínrọ̀ tẹ́ ẹ jíròrò dá lé lórí.
* Ẹ sì tún lè ṣàtúnyẹ̀wò àwọn “ẹsẹ tí ìkẹ́kọ̀ọ́ dá lé,” ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú, bí àyè bá ṣe wà sí.