Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ọ̀sẹ̀ April 17, 2006, sí January 1, 2007.
Ọ̀SẸ̀ ORÍ ÌPÍNRỌ̀ ÀFIKÚN
Apr. 17 1* 1 sí 13
Apr. 24 1 14 sí 24 ojú ìwé 195 sí 7
May 1 2 1 sí 17
May 8 2 18 sí 20 ojú ìwé 199 sí 201
May 15 3 1 sí 12
May 22 3 13 sí 24
May 29 4 1 sí 11 ojú ìwé 197 sí 9
June 5 4 12 sí 22 ojú ìwé 201 sí 4
June 12 5 1 sí 13 ojú ìwé 204 sí 6
June 19 5 14 sí 22 ojú ìwé 206 sí 8
June 26 6 1 sí 6 ojú ìwé 208 sí 11
July 3 6 7 sí 20
July 10 7 1 sí 15
July 17 7 16 sí 25 ojú ìwé 212 sí 15
July 24 8 1 sí 17
July 31 8 18 sí 23 ojú ìwé 215 sí 18
Aug. 7 9 1 sí 9 ojú ìwé 218 sí 19
Aug. 14 9 10 sí 18
Aug. 21 10 1 sí 9
Aug. 28 10 10 sí 19
Sept. 4 11 1 sí 11
Sept. 11 11 12 sí 21
Sept. 18 12 1 sí 16
Sept. 25 12 17 sí 22
Oct. 2 13 1 sí 9
Oct. 9 13 10 sí 19
Oct. 16 14 1 sí 13
Oct. 23 14 14 sí 21
Oct. 30 15 1 sí 14
Nov. 6 15 15 sí 20 ojú ìwé 219 sí 20
Nov. 13 16 1 sí 10 ojú ìwé 221 sí 2
Nov. 20 16 11 sí 19 ojú ìwé 222 sí 3
Nov. 27 17 1 sí 11
Dec. 4 17 12 sí 20
Dec. 11 18 1 sí 13
Dec. 18 18 14 sí 25
Dec. 25 19 1 sí 14
Jan. 1 19 15 sí 23
Ẹ ka àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a tọ́ka sí kẹ́ ẹ sì jíròrò wọn bí àkókò bá ṣe wà sí. Ẹ rí i pé ẹ ka gbogbo ìpínrọ̀ tá a yàn fún ọ̀sẹ̀ kọ̀ọ̀kan àti àfikún tá a bá yàn síbẹ̀. Ẹ jíròrò àpótí náà “Ohun Tí Bíbélì Fi Kọ́ni” lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti ka ìpínrọ̀ tó kẹ́yìn nínú orí náà.
* Fi ọ̀rọ̀ àkọ́sọ tó wà ní ojú ìwé 3 sí 7 kún un.