Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 453 125.9 35.4 59.8 14.5
Aṣá. Déédéé 27,824 53.9 16.9 21.3 6.0
Aṣá. Olù. 9,448 48.8 13.7 16.6 4.3
Akéde 264,680 10.9 4.3 4.2 1.3
ÀRÒPỌ̀ 302,405 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 183
Ìròyìn ọdún iṣẹ́ ìsìn 2007 yìí mà mórí ẹni wú o! Fúngbà àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà a ní akéde tó tó ẹgbàá mọ́kànléláàádọ́jọ àti irínwó lé márùn-ún [302,405]! Èyí múnú wa dùn gan-an ó sì jẹ́ ká túbọ̀ pinnu láti máa yin Jèhófà nítorí ó fi inú rere àti ìfẹ́ rẹ̀ hàn sí wa ní ti pé ó bù kún àwọn ìsapá wa.—Sm. 57:9.