Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 2
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 2
Orin 136
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jd orí 14 ìpínrọ̀ ¶1-9
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jẹ́nẹ́sísì 21-24
No. 1: Jẹ́nẹ́sísì 22:1-18
No. 2: “Èyí Ni Ọmọ Mi” (lr orí 5)
No. 3: Àwọn Ọ̀nà Tá A Lè Gbà Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn (2 Kọ́r. 6:11-13)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 220
5 min: Àwọn ìfilọ̀ ìjọ. Rán àwọn akéde létí pé kí wọ́n fi ìròyìn iṣẹ́ ìsìn pápá wọn ti ìparí oṣù January sílẹ̀.
10 min: Bẹ̀rù Ọlọ́run Tòótọ́, Kí O sì Pa Àwọn Àṣẹ Rẹ̀ Mọ́. Kí alàgbà kan fi ìtara sọ àsọyé yìí, a gbé e ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 272.
20 min: ‘Mímú Kí Ibi Àgọ́ Wa’ Túbọ̀ Láyè Gbígbòòrò ní Nàìjíríà—Apá Kìíní. Àsọyé àti ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka lẹ́tà ìròyìn tá a gbà pẹ̀lú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti oṣù November 2008.
Orin 194