ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 2/09 ojú ìwé 7
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 23
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2009
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 23
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2009
km 2/09 ojú ìwé 7

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 23

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 23

Orin 22

□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

lv-YR orí 1 ìpínrọ̀ 1 sí 9 àti ọ̀rọ̀ ìṣáájú

□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Jẹ́nẹ́sísì 32-35

Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run

□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 1

5min: Àwọn ìfilọ̀ ìjọ. Sọ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tá a máa lò lóṣù March.

10 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Ilé Ìṣọ́ March 1 àti Jí! January–March. Lẹ́yìn tó o bá ti sọ̀rọ̀ ṣókí lórí àwọn ìwé ìròyìn yìí, ní káwọn ará sọ àwọn àpilẹ̀kọ tó ṣeé ṣe kó fa àwọn èèyàn mọ́ra ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín, kí wọ́n sì sọ ìdí tí wọ́n fi rò bẹ́ẹ̀. Ní kí wọ́n mẹ́nu ba àwọn kókó kan tí wọ́n ní lọ́kàn láti lò nígbà tí wọ́n bá fẹ́ fi àwọn ìwé ìròyìn náà lọni lóde ẹ̀rí. Ìbéèrè wo ni wọ́n lè fi bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò? Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wo ni wọ́n máa fẹ́ kà? Níparí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣàṣefihàn ọ̀nà tá a lè gbà fi ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìwé ìròyìn náà lọni.

10 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.

10 min: Ṣé Ò Ń Lo Ìwé Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́? Àsọyé àti ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ọ̀rọ̀ ìṣáájú nínú ìwé Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2009. Sọ àwọn àǹfààní tó wà nínú ṣíṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ ojoojúmọ́ déédéé. Ní káwọn ara sọ ìgbà tí wọ́n máa ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ ojoojúmọ́ àti bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é, kí wọ́n sì sọ àǹfààní tí wọ́n ti jẹ.

Orin 160

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́