Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ March 9
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MARCH 9
Orin 202
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jẹ́nẹ́sísì 40-42
No. 1: Jẹ́nẹ́sísì 40:1-15
No. 2: A Gbọ́dọ̀ Kọ Ìdẹwò (lr orí 9)
No. 3: Ṣọ́ra fún Ẹ̀mí Tinú-Mi-Ni-Màá-Ṣe!
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 41
5 min: Àwọn ìfilọ̀. Ní káwọn ará sọ ìrírí kan tàbí méjì nípa bí wọ́n ṣe lo àwọn ìwé ìròyìn wa àti àbájáde rẹ̀.
15 min: Nígbà Tí Àwọn Èèyàn Bá Ní Ká Ṣàlàyé Ọ̀rọ̀. Àsọyé àti ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 177 ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 178 ìpínrọ̀ 3. Ṣàṣefihàn nípa bí akéde kan ṣe lè dáhùn ìbéèrè tí ọmọ ilé ìwé ẹ̀ tàbí ẹni tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ bi í nípa ohun tá a gbà gbọ́. Kí akéde náà dáhùn lọ́nà pẹ̀lẹ́, “pẹ̀lú inú tútù àti ọ̀wọ̀ jíjinlẹ̀.”—1 Pét. 3:15.
15 min: “Múra Sílẹ̀ Dáadáa fún Ìrántí Ikú Kristi.” Àsọyé àti ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Sọ ètò tí ìjọ ti ṣe nípa Ìrántí Ikú Kristi.
Orin 192