Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 27
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 27
rin 122
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 4 ìpínrọ̀ 12 sí 21, àti àpótí tó wà lójú ìwé 42
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ẹ́kísódù 19-22
Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
□ IÌpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 195
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
5 min: Àpótí Ìbéèrè.
25 min: “Àpéjọ Àgbègbè Ọdún 2009 ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.” Akọ̀wé ìjọ ni kó bójú tó iṣẹ́ yìí. Kẹ́ ẹ tó jíròrò àpilẹ̀kọ yìí, kọ́kọ́ ka lẹ́tà February 1, 2009, tá a fi yan ìjọ yín sí àpéjọ àgbègbè. Tẹ́nu mọ́ ìjẹ́pàtàkì fífi èso tẹ̀mí ṣèwà hù nígbà gbogbo.—Gál. 5:22, 23.
Orin 55