Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 31
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 31
Orin 132
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 9 ìpínrọ̀ 13 sí 21, àpótí tó wà lójú ìwé 104
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 17-21
Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 159
5 min: Àwọn ìfilọ̀. Rán àwọn ará létí pé kí wọ́n fi ìròyìn iṣẹ́ ìsìn pápá wọn ti oṣù August sílẹ̀.
10 min: Bá A Ṣe Lè Ṣàlàyé Kókó Kan, Ká sì Fi Ohun Tó Wà Lọ́kàn Hàn. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 237, ìpínrọ̀ 3, sí ojú ìwé 238, ìpínrọ̀ 5. O lè ṣàṣefihàn tó dá lórí kókó kan tàbí méjì nínú àpilẹ̀kọ náà.
20 min: “Ìpàdé fún Iṣẹ́ Ìsìn Pápá.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 151