Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 7
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 7
Orin 210
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 9 ìpínrọ̀ 22 sí 26, àpótí ojú ìwé 109, àfikún ojú ìwé 218 sí 219
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 22-25
No. 1: Númérì 22:20-35
No. 2: Bí Ọlọ́run Ṣe Dáàbò Bo Jésù (lr orí 32)
No. 3: Ìdí Tá A Fi Ń Bẹ Àwọn Èèyàn Wò Léraléra (td-YR 20B)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 167
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Bá A Ṣe Lè Dáhùn Ìbéèrè Nípa Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni orí 9, ojú ìwé 88 sí 94. Ṣàṣefihàn kan ní ṣókí.
10 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.
10 min: Ọ̀nà Tó Gbéṣẹ́ Láti Wá Àwọn Tó Fẹ́ Gbọ́ Rí. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 95, ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 96, ìpínrọ̀ 3. Ní káwọn ará sọ ìrírí kan tàbí méjì tó tayọ tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n ń wàásù lọ́nà míì tó yàtọ̀ sí ìwàásù ilé-dé-ilé, tàbí kí wọ́n ṣàṣefihàn rẹ̀.
Orin 39