Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 21
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 21
Orin 69
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 10 ìpínrọ̀ 9 sí 15, àpótí tó wà lójú ìwé 114
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 30-32
No. 1: Númérì 32:1-15
No. 2: Kí Ni Yóò Ṣẹlẹ̀ Bí A Bá Kú? (lr orí 34)
No. 3: Bá A Bá Ń Jẹ́rìí A Ò Ní Jẹ̀bi Ẹ̀jẹ̀ (td-YR 20D)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 141
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Ilé Ìṣọ́ October 1 àti Jí! July–September. Ní ṣókí, sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìwé ìròyìn náà. Ní káwọn ará sọ àpilẹ̀kọ inú Jí! July–September tí wọ́n rò pé ó máa fa àwọn èèyàn lọ́kàn mọ́ra ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu aṣáájú-ọ̀nà kan tó mọ bá a ṣe ń múra ìgbékalẹ̀ sílẹ̀ lọ́nà tó máa wọ àwọn èèyàn lọ́kàn, kó o sì jẹ́ kó ṣàṣefihàn kan tá a gbé karí Jí! July–September.
10 min: “Lo Bíbélì Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
10 min: “Báwo Lo Ṣe Máa Dáhùn?” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 107