Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 28
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 28
Orin 186
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 33-36
No. 1: Númérì 33:1-23
No. 2: A Lè Jí Dìde Kúrò Nínú Ikú! (lr orí 35)
No. 3: Àwọn Ọ̀nà Tí Ìjọba Ọlọ́run Fi Dára Ju Ìjọba Èèyàn Lọ
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 21
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Lo Àpèjúwe Tó O Bá Ń Kọ́ni. Àsọyé tá a gbé ka ìsọfúnni tó bá a mu nínú ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 240 sí 243.
20 min: “Wá Àwọn Ẹni Yíyẹ Kàn.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tàbí méjì tí wọ́n jẹ́ àwòfiṣàpẹẹrẹ ní ti wíwàásù lónírúurú ọ̀nà.
Orin 126