Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 18
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 18
Orin 210
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv orí 15 ìpínrọ̀ 18 sí 23 àti àpótí tó wà lójú ìwé 180
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Àwọn Onídàájọ́ 1-4
No. 1: Àwọn Onídàájọ́ 2:11-23
No. 2: Ọ̀rọ̀ Tí Ọlọ́run Mí sí Ni Bíbélì (td 8A)
No. 3: Ọlọ́run Kọ́ Ló Dá Èṣù
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Ní ṣókí sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìwé ìròyìn tá à ń lò lóṣù yìí, kó o wá sọ àwọn àpilẹ̀kọ tó o rò pé ó máa fa àwọn èèyàn lọ́kàn mọ́ra ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Ṣe àṣefihàn kan tó fi hàn bí ọ̀dọ́ akéde kan ṣe lè múra sílẹ̀ láti lo àwọn ìwé ìròyìn náà lóde ẹ̀rí.
15 min: Àpótí Ìbéèrè. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Ka àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a tọ́ka sí, kó o sì jíròrò wọn.