Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 25
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 25
Orin 143
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Àwọn Onídàájọ́ 5-7
No. 1: Àwọn Onídàájọ́ 7:1-11
No. 2: Báwo La Ṣe Lè Mọ “Aṣẹ́wó Ńlá” Tá A Ṣàpèjúwe ní Ìṣípayá 17:1?
No. 3: Bíbélì Jẹ́ Amọ̀nà Wíwúlò fún Ọjọ́ Wa (td 8B)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 185
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù February. Sọ̀rọ̀ ṣókí lórí àwọn àpilẹ̀kọ tẹ́ ẹ lè lò lóde ẹ̀rí nínú ìwé tá a máa lò lóṣù náà. Ṣàṣefihàn bí akéde kan ṣe lè lo ìwé náà láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì nígbà tó bá ń jẹ́rìí láìjẹ́ bí àṣà.
20 min: “Má Fi Falẹ̀!” Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Alàgbà ni kó bójú tó iṣẹ́ yìí. Ṣàṣefihàn bí akéde kan ṣe ń ṣàlàyé ìdí tá a fi ṣe káàdì DPA fún dókítà rẹ̀, ó sọ fún un pé kó fi káàdì náà sínú fáìlì òun. Dókítà náà ṣèlérí pé òun á ṣe bẹ́ẹ̀. Ka ìpínrọ̀ tó kẹ́yìn láti fi kádìí ọ̀rọ̀ rẹ.
Orin 160