ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 2/10 ojú ìwé 1
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 8
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2010
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 8
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2010
km 2/10 ojú ìwé 1

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 8

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 8

Orin 47

□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

lv orí 16 ìpínrọ̀ 15 sí 22 àti àpótí tó wà lójú ìwé 194

□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Àwọn Onídàájọ́ 11-14

No. 1: Àwọn Onídàájọ́ 13:1-14

No. 2: Kí Ni Ọ̀rọ̀ Jésù Tó Wà Nínú Lúùkù 16:9-13 Kọ́ Wa?

No. 3: Gbígba Ẹ̀jẹ̀ Sára Rú Òfin Ìjẹ́mímọ́ Ẹ̀jẹ̀ (td 11A)

□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 67

5 min: Àwọn ìfilọ̀.

10 min: Bá A Ṣe Lè Dáhùn Ìbéèrè Nípa Ọdún àti Àwọn Ayẹyẹ Kan. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 221 sí 223. Àwọn ìbéèrè wọ̀nyí ni kó o fún láfiyèsí: Àwọn ayẹyẹ wo ló ṣeé ṣe káwọn èèyàn ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín máa ṣe? Àwọn àkókò wo ló dáa láti bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ nípa ọdún àtàwọn ayẹyẹ kan, ibo ló sì ti yẹ ká bá wọn sọ̀rọ̀? Ṣe àṣefihàn bí òbí kan ṣe ń kọ́ ọmọ rẹ̀ bó ṣe máa dáhùn ìbéèrè náà, Kí nìdí tó o kì í fi í ṣayẹyẹ ọdún Àjíǹde?

20 min: “A Máa Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé!” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Tẹ́ ẹ bá ti rí ìwé ìkésíni gbà, ní kí wọ́n pín ọ̀kọ̀ọ̀kan fáwọn ará kẹ́ ẹ tó jíròrò ìpínrọ̀ 2, pàfiyèsí wọn sí oríṣiríṣi àwọn nǹkan tó wà nínú ìwé ìkésíni náà. Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá jíròrò ìpínrọ̀ 2, ní kí akéde kan ṣàṣefihàn bá a ṣe lè fún àwọn èèyàn ní ìwé ìkésíni náà. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu alábòójútó iṣẹ́ ìsìn tàbí alàgbà míì, kó ṣàlàyé síwájú sí i nípa ètò tí ìjọ ṣe fún òde ẹ̀rí nígbà tá a bá máa pín ìwé ìkésíni síbi Ìrántí Ikú Kristi.

Orin 114

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́