Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 19
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 19
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Sámúẹ́lì 23-25
No. 1: 1 Sámúẹ́lì 23:1-12
No. 2: Kí Ló Fa Ikú? (td 24A)
No. 3: Ìdí Tí Ìwà Ọ̀làwọ́ Fi Lérè (Òwe 11:25)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: “Kí Làwọn Èèyàn Máa Ń Kọ́ Lára Rẹ?” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
15 min: Àpótí Ìbéèrè. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Ka àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a tọ́ka sí kó o sì jíròrò wọn.