Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ May 24
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MAY 24
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Sámúẹ́lì 13-15
No. 1: 2 Sámúẹ́lì 13:23-33
No. 2: Èṣù Ni Ẹni Tí A Kò Lè Rí Tó Ń Ṣàkóso Ayé (td 10B)
No. 3: Ìdí Tí A Kò Fi Gbọ́dọ̀ Lo Ayé Dé Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ (1 Kọ́r. 7:31)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Àwọn Ìwé Ìròyìn ní Oṣù June. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Láàárín ìṣẹ́jú kan sí méjì, mẹ́nu ba ohun tó wà nínú àwọn ìwé ìròyìn tá a máa lò. Lẹ́yìn náà kó o yan àpilẹ̀kọ méjì tàbí mẹ́ta nínú àwọn ìwé ìròyìn náà, kó o wá ní kí àwùjọ sọ ìbéèrè àti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tí wọ́n lè fi gbé ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀. Ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè fi ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìwé ìròyìn náà lọni.
20 min: “O Lè Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà!” Ìbéèrè àti ìdáhùn.