Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 6
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 6
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Kíróníkà 10-14
No. 1: 2 Kíróníkà 13:1-12
No. 2: Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Ṣọ́ Àwọn Ẹni Ìdúróṣinṣin Rẹ̀? (Sm. 37:28)
No. 3: Ìdí Tí Ìgbàgbọ́ Nínú Jésù Fi Ṣe Kókó fún Ìgbàlà (td 35B)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àwọn ìfilọ̀. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ náà, Kí Ló Wà Nínú Bíbélì lọni tàbí nígbà tí wọ́n fi ìwé pẹlẹbẹ náà bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
15 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.
10 min: Bá A Ṣe Lè Máa Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Èèyàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́. Ìjíròrò tá a gbé ka Ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 190 sí 192, ìpínrọ̀ 2.