Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 17
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 17
Orin 77 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cf orí 16 ìpínrọ̀ 7 sí 14 (25 min)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ẹ́sírà 1-5 (10 min)
No. 1: Ẹ́sírà 3:1-9 (ìṣẹ́jú 4 tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ohun Tí “Òpin Ayé” Túmọ̀ Sí—td 39A (5 min)
No. 3: Báwo Ni Ẹ̀mí Ṣe Ń Pa Dà Sọ́dọ̀ Ọlọ́run?—Oní. 12:7 (5 min)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Àǹfààní Tó Wà Nínú Sísọ Àsọtúnsọ Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Pápá. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 206 sí 207. Ní ṣókí, ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì látinú àpilẹ̀kọ náà.
20 min: “Ṣó O Mọ Èyí Tó Yẹ Kó O Yàn?” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Fi ìsọfúnni tó wà ní ìpínrọ̀ 1 bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò náà, kó o sì fi ìsọfúnni tó wà ní ìpínrọ̀ 3 parí ìjíròrò náà. Alàgbà ni kó bójú tó iṣẹ́ yìí.
Orin 7 àti Àdúrà