Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ February 7
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 7
Orin 25 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cf orí 17 ìpínrọ̀ 10 sí 15 (25 min)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Nehemáyà 5-8 (10 min)
No. 1: Nehemáyà 6:1-13 (ìṣẹ́jú 4 tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ẹ̀kọ́ Wo La Rí Kọ́ Nípa Àlejò Ṣíṣe Látinú Àpẹẹrẹ Lìdíà, Gáyọ́sì àti Fílémónì? (5 min)
No. 3: Àwọn Wo Ló Ń Lọ sí Ọ̀run?—td 33B (5 min)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Ṣé Ò Ń Lo Ẹ̀bùn Rẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́? Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 75 ìpínrọ̀ 4, sí ojú ìwé 76, ìpínrọ̀ 2.
10 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.
10 min: Ọ̀rọ̀ Tó Jóòótọ́ Ni Kó O Máa Sọ Nígbà Tó O Bá Ń Wàásù àti Tó O Bá Ń Kọ́ni. Ìjíròrò tó dá lé ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 223, ìpínrọ̀ 1 sí 5.
Orin 13 àti Àdúrà