Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ July 4
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JULY 4
Orin 85 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 6 ìpínrọ̀ 1 sí 8, àti àpótí tó wà lójú ìwé 44 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Sáàmù 60-68 (10 min.)
No. 1: Sáàmù 62:1–63:5 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ọ̀nà Wo La Gbà Ń Kópa Nínú Ìmúṣẹ Hágáì 2:7? (5 min.)
No. 3: Ṣé Pétérù ni “Àpáta Ràbàtà”?—td 43B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Bí Ẹnìkan Bá Sọ Pé—‘Mo Ní Ìsìn Tèmi.’ Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé kékeré náà, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó, ojú ìwé 10, ìpínrọ̀ 2 sí ojú ìwé 11, ìpínrọ̀ 4. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ọ̀nà míì tí wọ́n ti gbà fèsì tó sì yọrí sí rere. Ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
10 min: Kí La Rí Kọ́? Ìjíròrò. Ẹ ka Lúùkù 9:57-62 àti Lúùkù 14:25-33. Ṣàgbéyẹ̀wò bí àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.
10 min: Àwọn Ọ̀ràn Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ.
Orin 124 àti Àdúrà