Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 8
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 8
Orin 44 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 7 ìpínrọ̀ 14 sí 18, àti àpótí tó wà lójú ìwé 57 sí 58 (25 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Sáàmù 92-101 (10 min.)
No. 1: Sáàmù 94:1-23 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Kí Ló Ń Fa Ikú?—td 24A (5 min.)
No. 3: Dènà Agbára Ìtannijẹ Ọrọ̀—Mát. 13:22 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
30 min: “A Máa Gbádùn Ìtura Nípa Tẹ̀mí fún Ọjọ́ Mẹ́ta.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Jíròrò “Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè Ọdún 2011.” Nígbà tó o bá ń jíròrò ìpínrọ̀ 5, ní kí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn sọ ètò tí ìjọ ṣe láti pín ìwé ìkésíni.
Orin 119 àti Àdúrà