Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 21
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 21
Orin 53 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 13 ìpínrọ̀ 1 sí 7, àti àpótí tó wà lójú ìwé 100 àti 103 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Oníwàásù 7-12 (10 min.)
No. 1: Oníwàásù 9:13–10:11 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìfẹ́ Kì Í Jowú—1 Kọ́r. 13:4 (5 min.)
No. 3: Àwọn Wo Ló Ń Lọ sí Ọ̀run?—td 41A (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àwọn Ìfilọ̀. Àpótí Ìbéèrè. Àsọyé.
15 min: “Ànímọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Tó Yẹ Kí Olùkọ́ Tó Dáńgájíá Ní.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní kí àwọn ará sọ bí ìfẹ́ tí ẹni tó kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fi hàn sí wọn ṣe jẹ́ kí wọ́n lè tẹ̀síwájú nípa tẹ̀mí.
10 min: “Kí Ìfẹ́ Ọlọ́run Ṣẹ.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ọjọ́ tẹ́ ẹ máa lọ sí àpéjọ àkànṣe yín, tẹ́ ẹ bá ti mọ̀ ọ́n.
Orin 35 àti Àdúrà