ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 11/11 ojú ìwé 8
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 5

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 5
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 5
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
km 11/11 ojú ìwé 8

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 5

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 5

Orin 29 àti Àdúrà

□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

bt orí 13 ìpínrọ̀ 17 sí 24 (25 min.)

□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Aísáyà 1-5 (10 min.)

No. 1: Aísáyà 3:16–4:6 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Rántí Pé Àkókò Kánjúkánjú Là Ń Gbé? (5 min.)

No. 3: Iná Ṣàpẹẹrẹ Ìparun Yán-án Yán-án—td 16B (5 min.)

□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 111

12 min: Àwọn Ìfilọ̀. Bí Ẹnì Kan Bá Béèrè Lọ́wọ́ Rẹ Pé Kí Nìdí Tí O Kò Fi Ṣayẹyẹ Kérésìmesì. Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ December 15, 2007, ojú ìwé 9. Ṣe àṣefihàn kúkúrú kan.

15 min: Wọ́n Ṣe Inúnibíni Sí Wọ́n Nítorí Pé Wọ́n Ń Wàásù. (Lúùkù 21:12, 13) Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ September 15, 2010, ojú ìwé 3 àti 4; January 15, 2006, ojú ìwé 27 àti 28; November 1, 1997, ojú ìwé 20. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.

8 min: Múra Sílẹ̀ fún Ìṣẹ́ Ìsìn Pápá. Ìjíròrò tó dá lórí àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí. (1) Báwo lo ṣe máa ń múra sílẹ̀ fún: (a) ìwàásù ilé-dé-ilé? (b) ìpadàbẹ̀wò? (c) ìjẹ́rìí àìjẹ́bí-àṣà? (2) Kí nìdí tó fi yẹ ká máa múra sílẹ̀ ní gbogbo ìgbà tá a bá fẹ́ darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (3) Kí lo máa ń ṣe láti ran ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́wọ́ kó lè máa múra ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ sílẹ̀? (4) Báwo ni ìmúrasílẹ̀ ṣe máa ń jẹ́ kó o gbádùn iṣẹ́ ìsìn pápá? (5) Kí nìdí tí inú Jèhófà fi máa ń dùn tá a bá múra iṣẹ́ ìsìn pápá sílẹ̀?

Orin 101 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́