Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní January 30
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 30
Orin 30 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 16 ìpínrọ̀ 1 sí 7 àti àpótí tó wà ní ojú ìwé 128 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Aísáyà 43-46 (10 min.)
No. 1: Aísáyà 45:15-25 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Bí Sùúrù Ọlọ́run Ṣe Ń Yọrí sí Ìgbàlà—2 Pét. 3:9, 15 (5 min.)
No. 3: Ṣé Gbogbo Ìsìn Ló Dára?—td 5B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀. Lo àbá tó wà lójú ìwé 4 láti ṣe àṣefihàn béèyàn ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Saturday àkọ́kọ́ lóṣù February.
10 min: Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìkànnì Àjọlò Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì?—Apá 1. Àsọyé tá a gbé ka Jí! January–March 2012, ojú ìwé 16 sí 19.
20 min: “Ǹjẹ́ O Ti Múra Sílẹ̀ De Ìtọ́jú Pàjáwìrì?” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní ṣókí, fi àlàyé tó wà ní ìpínrọ̀ àkọ́kọ́ nasẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ, kí o sì fi ìpínrọ̀ tó gbẹ̀yìn parí ọ̀rọ̀ rẹ. Ẹ lè lo “Bí Àwọn Òbí Ṣe Lè Dáàbò Bo Ọmọ Wọn Kí Wọ́n Má Bàa Fa Ẹ̀jẹ̀ Sí Wọn Lára” (S-55) rọ́pò rẹ̀. Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí.
Orin 116 àti Àdúrà