Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní April 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 23
Orin 45 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 19 ìpínrọ̀ 12 sí 20, àti àpótí tó wà ní ojú ìwé 152 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jeremáyà 29-31 (10 min.)
No. 1: Jeremáyà 31:15-26 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ǹjẹ́ Ọlọ́run Retí Pé Kí Àwọn Kristẹni Máa Pa Sábáàtì Mọ́? (5 min.)
No. 3: Wà Lójúfò Nípa Tẹ̀mí Kó O Lè Mọ Àwọn Àmì Tó Fi Hàn Pé A Ti Wà Ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn—td 39B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àwọn Ìfilọ̀. Lo ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tó wà lójú ìwé 4 láti fi ṣàṣefihàn bá a ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Saturday àkọ́kọ́ lóṣù May.
10 min: Bó O Ṣe Lè Dá Ẹni Tó Sọ Pé Òun Kò Nífẹ̀ẹ́ sí Ọ̀rọ̀ Ìsìn Lóhùn. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé kékeré náà, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó, ojú ìwé 9, ìpínrọ̀ 2 sí ojú ìwé 11, ìpínrọ̀ 2. Ní ṣókí, ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
15 min: “Ìgbà Nínífẹ̀ẹ́ àti Ìgbà Kíkórìíra.” Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ December 1, 2011, ojú ìwé 23 sí 25.
Orin 70 àti Àdúrà