Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní June 18
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 18
Orin 61 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 22 ìpínrọ̀ 7 sí 14, àti àpótí tó wà lójú ìwé 174 àti 177 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ìdárò 3-5 (10 min.)
No. 1: Ìdárò 5:1-22 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ẹni Tó Jẹ́ Kristẹni Nìkan Ni Kristẹni Kan Gbọ́dọ̀ Fẹ́—td 19E (5 min.)
No. 3: Ìdí Tá A Fi Gbàgbọ́ Pé Ọlọ́run Mí Sí Bíbélì—2 Tím. 3:16 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àwọn Ìfilọ̀. Àpótí Ìbéèrè. Àsọyé.
10 min: Ǹjẹ́ O Rántí? Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ April 15, 2012, ojú ìwé 32.
15 min: Àwọn Ìwé Ìkẹ́kọ̀ọ́ Wa Ṣe Pàtàkì. Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ August 15, 2003, ojú ìwé 29. Ní kí àwọn ará sọ ohun tí wọ́n kọ́.
Orin 24 àti Àdúrà