Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 17
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 17
Orin 97 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 2 ìpínrọ̀ 20 sí 27 àti àpótí tó wà lójú ìwé 29 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Sekaráyà 1-8 (10 min.)
No. 1: Sekaráyà 8:1-13 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Bá A Ṣe Ń Fi Hàn Pé Jèhófà Ni Olúwa Ọba Aláṣẹ Wa—Sm. 73:28 (5 min.)
No. 3: Àwọn Ohun Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Ayé Báyìí Fi Hàn Pé Kristi Ti Dé—td 26B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
15 min: Ìhìn Tí A Ní Láti Polongo—“Bẹ̀rù Ọlọ́run Tòótọ́, Kí O Sì Pa Àwọn Àṣẹ Rẹ̀ Mọ́.” Àsọyé tó ń tani jí, tá a gbé ka ìwé Jàǹfààní Nínú Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 272 sí ìsọ̀rí tó wà lójú ìwé 275.
15 min: “Máa Ṣọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ọjọ́ tẹ́ ẹ máa lọ sí àpéjọ àkànṣe yín, tẹ́ ẹ bá ti mọ̀ ọ́n.
Orin 117 àti Àdúrà