Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 31
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 31, 2012
Orin 60 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 3 ìpínrọ̀ 7 sí 12 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Málákì 1-4 (10 min.)
Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run (20 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: “Àpilẹ̀kọ Tuntun Tí Yóò Máa Jáde Nínú Ilé Ìṣọ́.” Àsọyé. Lo àbá tó wà lójú ìwé 8 láti ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Sátidé àkọ́kọ́ lóṣù January.
10 min: Kí La Rí Kọ́? Ìjíròrò. Ẹ ka Lúùkù 10:38-42, kẹ́ ẹ sì jíròrò bí ohun tó wà níbẹ̀ ṣe lè wúlò fún wa lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́.
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù January àti February. Ìjíròrò. Sọ àwọn kókó pàtàkì tó ṣeé ṣe káwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ sí nínú àwọn ìwé náà, kó o sì ṣe àṣefihàn méjì.
Orin 134 àti Àdúrà