Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 14
Orin 52 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 4 ìpínrọ̀ 1 sí 8 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Mátíù 7-11 (10 min.)
No. 1: Mátíù 10:24-42 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Lo Ìfòyemọ̀, Má sì Ṣe Tẹ̀ Lé “Òtúbáńtẹ́”—1 Sám. 12:21; Òwe 23:4, 5 (5 min.)
No. 3: Ìgbà Wo Ni Sábáàtì Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Tó sì Parí?—td 42D (5 min.)
□ Ìpàdé Ìṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Ṣèrànwọ́ fún Wọn Nípa Ti Ara. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run ojú ìwé 188, ìpínrọ̀ 4 sí ojú ìwé 189, ìpínrọ̀ 4. Ní ṣókí, fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu ẹnì kan tó ti tẹ̀ síwájú nítorí pé ó rí ìrànlọ́wọ́ gbà látọ̀dọ̀ àwọn tó fi hàn pé ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ àwọn lógún.
10 min: Kí La Rí Kọ́? Ìjíròrò. Ẹ ka Mátíù 4:1-11. Ẹ jíròrò bí àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.
10 min: “Máa ‘Jẹ́rìí Kúnnákúnná.’” Ìbéèrè àti Ìdáhùn.
Orin 92 àti Àdúrà