ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 4/13 ojú ìwé 1
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 8
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 8
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
km 4/13 ojú ìwé 1

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 8

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 8

Orin 123 àti Àdúrà

□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

jr orí 7 ìpínrọ̀ 14 sí 20 (30 min.)

□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Lúùkù 10-12 (10 min.)

No. 1: Lúùkù 12:1-21 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Jèhófà Kì Í Ṣe Mẹ́talọ́kan—td 36A (5 min.)

No. 3: Ìdí Tá A Fi Gbà Pé Jèhófà Jẹ́ Baba Wa—Mát. 6:9 (5 min.)

□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 60

10 min: Máa Fún Wọn Ní Ìṣírí. (Róòmù 1:11, 12) Ìjíròrò tí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn máa bójú tó. Sọ iye aṣáájú-ọ̀nà déédéé tó wà ní ìjọ yín. Sọ àwọn ọ̀nà tá a lè gbà fún wọn ní ìṣírí, irú bíi ká máa gbóríyìn fún wọn, ká máa ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wọn lóde ẹ̀rí, ká máa san owó ọkọ̀ wọn tàbí ká máa pè wọ́n láti wá kí wa nílé. Ní kí àwọn aṣáájú-ọ̀nà sọ bí àwọn kan ṣe fún wọn ní ìṣírí. Tí ẹ kò bá ní aṣáájú-ọ̀nà déédéé kankan ní ìjọ yín, ẹ jẹ́ kí ìjíròrò yìí dá lórí àwọn aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́.

10 min: Bá A Ṣe Lè Dáhùn Ìbéèrè Nípa Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 88, ìpínrọ̀ 6 sí ojú ìwé 92, ìpínrọ̀ 14. Ṣe àṣefihàn kan tó dá lórí bí akéde kan ṣe ń ṣàlàyé àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé àwọn ọjọ́ ìkẹyìn la wà yìí.

10 min: “Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Wòlíì—Jónà.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.

Orin 13 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́