Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 30
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 30
Orin 99 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 14 ìpínrọ̀ 20 sí 25 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Gálátíà 1-6 (10 min.)
No. 1: Gálátíà 1:18–2:10 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìgbà Wo Ni Àkókò Àwọn Kèfèrí Dópin?—td 30A (5 min.)
No. 3: Ìdí Tí Jèhófà Fi Yẹ Lẹ́ni Tó Yẹ Ká Máa Sìn—Ìṣí. 4:11 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: “Ṣé O Lè Ké sí Wọn?” Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, ṣe àṣefihàn bí ẹ ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Sátidé àkọ́kọ́ lóṣù October.
10 min: Àwọn Ọ̀nà Tá A Gbà Ń Wàásù Ìhìn Rere—Bó O Ṣe Lè Wàásù fún Onírúurú Èèyàn Tí Èdè Wọn Yàtọ̀ Síra. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 104, ìpínrọ̀ 2, sí ojú ìwé 105, ìpínrọ̀ 3. Ṣe àṣefihàn kan.
10 min: Ẹ Má Ṣe Ṣàníyàn Láé. (Mát. 6:31-33) Ìjíròrò tá a gbé ka Ìwé Ọdọọdún 2013, ojú ìwé 138, ìpínrọ̀ 2, sí ojú ìwé 139, ìpínrọ̀ 1. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
Orin 40 àti Àdúrà