ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 3/14 ojú ìwé 4
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 7

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 7
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 7
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
km 3/14 ojú ìwé 4

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 7

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 7

Orin 15 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

cl orí 5 ìpínrọ̀ 9 sí 17 (30 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Ẹ́kísódù 7-10 (10 min.)

No. 1: Ẹ́kísódù 9:20-35 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Èrò Àwọn Kristẹni Nípa Àwọn Ayẹyẹ—td 38A (5 min.)

No. 3: Àwọn Tó Di Ọmọ Ẹ̀yìn Jésù—lr orí 13 (5 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 124

10 min: Ohun tó ń fẹ́ abojútó nínú ìjọ. Akọ̀wé ni kó bójú tó apá yìí. Kó sọ ọ́ bí àsọyé tá a gbé ka àpéjọ àgbègbè ti ọdún 2014.

10 min: Ẹ Má Ṣe Gbàgbé Aájò Àlejò. (Héb. 13:1, 2) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. Sọ àwọn ètò tí ìjọ ṣe fún Ìrántí Ikú Kristi. Sọ àwọn ọ̀nà tí gbogbo àwọn ará lè gbà ṣe aájò àwọn tó jẹ́ àlejò àtàwọn akéde tó ti di aláìṣiṣẹ́mọ́ tó bá wá síbi Ìrántí Ikú Kristi. Ṣe àṣefihàn alápá méjì ní ṣókí. Nínú àṣefihàn àkọ́kọ́, kí akéde kan máa kí ẹnì kan tó gba ìwé ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi káàbọ̀. Lẹ́yìn náà, kí akéde náà tún lọ bá ẹni náà lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí kó lè bá a ṣe àdéhùn bá a ṣe máa kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

10 min: Báwo La Ṣe Ṣe Sí? Ìjíròrò. Ní kí àwọn ará sọ bí wọ́n ṣe jàǹfààní nígbà tí wọ́n lo àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ náà, “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bó O Ṣe Lè Fèsì Bí Ẹnì Kan Ò Bá Fẹ́ Gbọ́ Ìwàásù Rẹ.” Ní kí wọ́n sọ àwọn ìrírí tó gbádùn mọ́ni tí wọ́n ní.

Orin 20 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́