ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 11/14 ojú ìwé 2
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 17
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 17
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
km 11/14 ojú ìwé 2

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 17

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 17

Orin 26 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

cl orí 16 ìpínrọ̀ 1 sí 9 (30 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Diutarónómì 23-​27 (10 min.)

No. 1: Diutarónómì 25:⁠17–​26:10 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Ṣíṣe Ayẹyẹ Máàsì Kò Bá Ìwé Mímọ́ Mu​—⁠td 28B (5 min.)

No. 3: Ọlọ́run Rántí Ọmọ Rẹ̀—​lr orí 39 (5 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 118

10 min: Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́? Ìjíròrò tá a gbé ka eré ojú pátákó tá a pe àkọlé rẹ̀ ní, Ta Ni Ọ̀rẹ́ ­Tòótọ́? (Lọ sórí ìkànnì jw.org/yo, wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ ­BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.) Kọ́kọ́ fi fídíò náà han àwọn ará. Lẹ́yìn náà, kí ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: (1) Ta ni ọ̀rẹ́ tòótọ́? (2) Àwọn ànímọ́ wo ló yẹ kó o wò lára ẹni tó o fẹ́ fi ṣe ọ̀rẹ́? (3) Báwo lo ṣe lè ní ọ̀rẹ́ tó dáa? (4) Kí ló yẹ kó o máa ṣe kí ìwọ àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ lè máa bá ara yín ṣọ̀rẹ́ lọ? Ní ­àfidípò, ẹ jíròrò àwọn àpótí tó wà lójú ìwé 29 àti 30 nínú ìwé Ìfẹ́ Ọlọ́run

10 min: Ìfẹ́ Ni A Fi Ń Dá Wa Mọ̀. (Jòhánù 13:35) Ìjíròrò tó dá lórí Ìwé Ọdọọdún 2014, ojú ìwé 48, ìpínrọ̀ 1 sí ojú ìwé 49 ìpínrọ̀ 3 àti ojú ìwé 69 ìpínrọ̀ 1 sí ojú ìwé 70 ìpínrọ̀ 2. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.

10 min: “Ọ̀nà Tuntun Tó Lárinrin Tá A Ó Máa Gbà Wàásù Láwọn Ibi Tí Èrò Pọ̀ Sí.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Tí àwọn ibi tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń gbà kọjá bá wà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù ìjọ yín, fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu alábòójútó iṣẹ́ ìsìn nípa ètò tí ìjọ ṣe láti máa wàásù láwọn ibi tí èrò pọ̀ sí yìí. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní.

Orin 92 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́