Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 13
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 13
Orin 18 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cl orí 23 ìpínrọ̀ 1 sí 9 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Sámúẹ́lì 19-22 (8 min.)
No. 1: 1 Sámúẹ́lì 21:10–22:4 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Ṣọ́ Àwọn Ẹni Ìdúróṣinṣin Rẹ̀?—Sm. 37:28 (5 min.)
No. 3: Kí Nìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Jìyà?—igw ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 1 sí 4 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
ẸṢIN Ọ̀RỌ̀ OṢÙ YÌÍ: Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọlọgbọ́n nípa “ríra àkókò tí ó rọgbọ padà.”—Éfé. 5:15, 16.
10 min: Ẹ Máa Rìn Gẹ́gẹ́ Bí Ọlọgbọ́n Nípa “Ríra Àkókò Tí Ó Rọgbọ Padà.” Àsọyé tó dá lórí ẹṣin ọ̀rọ̀ oṣù yìí.—Éfé. 5:15, 16; wo Ilé Ìṣọ́ May 15, 2012, ojú ìwé 19 sí 20 ìpínrọ̀ 11 sí 14.
20 min: “Máa Ra Àkókò Tí Ó Rọgbọ Pa Dà Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́.” Ìjíròrò.
Orin 98 àti Àdúrà