Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní July àti August: Ẹ lo èyíkéyìí lára àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n yìí: Tẹ́tí sí Ọlọ́run, Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé, Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ṣé O Ti Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? àti Ìwọ́ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run! September àti October: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!