ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 8/15 ojú ìwé 3
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 24
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 24
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
km 8/15 ojú ìwé 3

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 24

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 24

Orin 21 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

cl orí 29 ìpínrọ̀ 11 sí 15 (30 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 5-8 (8 min.)

No. 1: 2 Àwọn Ọba 6:20-31 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Kí Ló Wà Nínú Oríṣiríṣi Ìwé Tó Para Pọ̀ Di Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù?​—igw ojú ìwé 30 (5 min.)

No. 3: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jèhófà àti Jésù Nípa Híhùwà Ọmọlúwàbí (5 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

ẸṢIN Ọ̀RỌ̀ OṢÙ YÌÍ: “Ní tèmi àti agbo ilé mi, Jèhófà ni àwa yóò máa sìn.”​—Jóṣ. 24:15.

Orin 40

10 min: Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.

10 min: Fi Àwọn Ìwé Ìròyìn Lọni Lóṣù September. Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tó wà lójú ìwé yìí ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè fi àwọn ìwé ìròyìn náà lọni. Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ náà láti ìbẹ̀rẹ̀ dópin.

10 min: Báwo Lo Ṣe Lè Mú Kí Ìjọsìn Ìdílé Rẹ Sunwọ̀n Sí I? Ìjíròrò tó dá lórí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti January 2011 ojú ìwé 6. Pe àfiyèsí àwọn ará sí onírúurú iṣẹ́ Ìjọsìn Ìdílé tí gbogbo àwọn tó wà nínú ìdílé lè jọ máa ṣe nígbà ìjọsìn ìdílé wọn bó ṣe wà lórí ìkànnì jw.org/yo. (Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Tẹnu mọ́ ọn pé ó yẹ kí ohun tí a ó máa jíròrò nígbà ìjọsìn ìdílé bá ipò ìdílé mu, kó sì fún ìgbàgbọ́ ìdílé náà nínú Jèhófà àti àwọn ìlérí rẹ̀ lágbára.

Orin 130 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́