ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 9/15 ojú ìwé 2
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 21

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 21
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 21
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
km 9/15 ojú ìwé 2

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 21

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 21

Orin 53 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

cl orí 30 ìpínrọ̀ 19 sí 23, àpótí tó wà lójú ìwé 309 (30 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 19-22 (8 min.)

No. 1: 2 Àwọn Ọba 20:​12-21 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Kí Ló Mú Kí Ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù Tó Wà ní Róòmù 14:​7-9 Tù Wá Nínú? (5 min.)

No. 3: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Mọ Orúkọ Ọlọ́run Ká sì Máa Lò Ó?​—wp13 1/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 1 sí 4 (5 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

ẸṢIN Ọ̀RỌ̀ OṢÙ YÌÍ: “Jẹ́rìí kúnnákúnná sí ìhìn rere.”​—Ìṣe 20:24.

Orin 97

10 min: Báwo La Ṣe Ṣe Sí Lọ́dún Iṣẹ́ Ìsìn Tó Kọjá? Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó sọ àsọyé yìí. Sọ̀rọ̀ nípa bí ìjọ yín ṣe ṣe sí lọ́dún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá. Tẹnu mọ́ àwọn àṣeyọrí tẹ́ ẹ ṣe, kó o sì gbóríyìn fún àwọn ará. Mẹ́nu ba apá ibì kan tàbí méjì tó yẹ kí ìjọ yín ṣiṣẹ́ lé lórí lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tá a wà yìí, kó o sì sọ àwọn ohun tẹ́ ẹ lè ṣe láti tẹ̀ síwájú.

10 min: Bá A Ṣe Ń Jẹ́rìí Kúnnákúnná Ń Méso Rere Jáde. Ìjíròrò tó dá lórí Ìwé Ọdọọdún 2015, ojú ìwé 54, ìpínrọ̀ 1; ojú ìwé 56, ìpínrọ̀ 2 sí ojú ìwé 57, ìpínrọ̀ 1 àti ojú ìwé 63, ìpínrọ̀ 2 sí ojú ìwé 64, ìpínrọ̀ 1. Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti jíròrò àwọn ìrírí náà tán lọ́kọ̀ọ̀kan, ní kí àwọn ará sọ àwọn ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.

10 min: “Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.

Orin 81 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́