Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 14
Orin 50 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
ia orí 4 ìpínrọ̀ 16 sí 31, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 41 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Kíróníkà 15-19 (8 min.)
No. 1: 2 Kíróníkà 16:1-9 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà, Báwo Ló sì Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà?—wp14 7/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 1 sí 4 (5 min.)
No. 3: Ìdí Tí Ìfẹ́ Kì Í Fi Í Kùnà Láé—1 Kọ́r. 13:8; 1 Jòh. 4:8 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Ẹṣin Ọ̀rọ̀ Oṣù Yìí: “A gbọ́dọ̀ ti inú ọ̀pọ̀ ìpọ́njú wọ ìjọba Ọlọ́run.”—Ìṣe 14:22.
30 min: “Ẹ Máa Ní Ìfẹ́ fún Gbogbo Ẹgbẹ́ Àwọn Ará.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní ṣókí, fi àlàyé tó wà ní ìpínrọ̀ àkọ́kọ́ nasẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ, kí o sì fi èyí tó wà ní ìpínrọ̀ tó gbẹ̀yìn parí ọ̀rọ̀ rẹ.
Orin 133 àti Àdúrà