ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 6
  • December 19-25

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 19-25
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 6

December 19-25

AÍSÁYÀ 11-16

  • Orin 143 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà”: (10 min.)

    • Ais 11:3-5​—Òdodo yóò gbilẹ̀ títí láé (ip-1 ojú ìwé 160 àti 161 ìpínrọ̀ 9 sí 11)

    • Ais 11:6-8​—Àlááfíà máa wà láàárín àwọn èèyàn àti ẹranko (w12 9/15 ojú ìwé 9 àti 10 ìpínrọ̀ 8 àti 9)

    • Ais 11:9​—Gbogbo èèyàn máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà (w16.06 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 9; w13 6/1 ojú ìwé 7)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 11:1, 10​—Báwo ni Jésù Kristi ṣe lè jẹ́ “gbòǹgbò Jésè” síbẹ̀ kó tún jẹ́ ẹ̀ka igi kan tó yọ láti “ara kùkùté Jésè”? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 6)

    • Ais 13:17​—Ọ̀nà wo làwọn ará Mídíà kò fi ka fàdákà sí ohunkóhun tí Wọn kò sì ní inú dídùn sí wúrà? (w06 12/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 10)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 13:17–14:8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Job 34:10​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 8:9; 1Jo 5:19​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 54 ìpínrọ̀ 9​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 24

  • “Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Johny àti Gideon: Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Wọ́n Ti Di Arákùnrin Báyìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 5 ìpínrọ̀ 18 sí 25, àpótí “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 151 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́