December Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé December 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò December 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 1-5 ‘Ẹ Jẹ́ Kí A Gòkè Lọ sí Òkè Ńlá Jèhófà’ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I— Máa Lo Ìwé “Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run” Láti Dénú Ọkàn Àwọn Èèyàn December 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 6-10 Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Tó Ní Ìmúṣẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Èmi Nìyí! Rán Mi!” December 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 11-16 Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú December 26, 2016–January 1, 2017 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 17 SÍ 23 Àṣẹ Máa Ń Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹni Tó Bá Ń Ṣi Agbára Lò