ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 3
  • ‘Ẹ Jẹ́ Kí A Gòkè Lọ sí Òkè Ńlá Jèhófà’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Ẹ Jẹ́ Kí A Gòkè Lọ sí Òkè Ńlá Jèhófà’
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Gbé Ilé Jèhófà Lékè
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní
  • Òpin Pátápátá Sí Ìwà Ipá—Báwo?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Ìṣọ̀kan Ìjọsìn ní Àkókò Wa—Kí Ló Túmọ̀ Sí?
    Jọ́sìn Ọlọ́run Tòótọ́ Kan Ṣoṣo Náà
  • Ayé Kan Láìsí Ogun Yóò Dé Láìpẹ́
    Jí!—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN |  AÍSÁYÀ 1-5

‘Ẹ Jẹ́ Kí A Gòkè Lọ sí Òkè Ńlá Jèhófà’

2:2, 3

“Apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́”

Àkókò tí à ń gbé yìí

“Òkè ńlá ilé Jèhófà”

Ìjọsìn mímọ́ tó jẹ́ ti Jèhófà

“Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì máa wọ́ tìrítìrí lọ sórí rẹ̀”

Àwọn tó ń ṣe ìjọsìn mímọ́ máa ń pàdé pọ̀ ní ìṣọ̀kan

“Ẹ wá, ẹ sì jẹ́ kí a gòkè lọ sí òkè ńlá Jèhófà”

Àwọn olùjọ́sìn tòótọ́ máa ń pe àwọn míì láti dara pọ̀ mọ́ wọn

“Òun yóò sì fún wa ní ìtọ́ni nípa àwọn ọ̀nà rẹ̀, àwa yóò sì máa rìn ní àwọn ipa ọ̀nà rẹ”

• Jèhófà máa ń lo Ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti tọ́ wa sọ́nà àti láti ràn wá lọ́wọ́, ká lè máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀

Àwọn èèyàn láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ń gòkè lọ sí òkè ńlá ilé Jèhófà

2:4

“Bẹ́ẹ̀ ni wọn kì yóò kọ́ṣẹ́ ogun mọ́”

Aísáyà ṣàpèjúwe bá a ṣe máa yí àwọn ohun ìjà ogun pa dà sí ohun èlò téèyàn lè fi ṣiṣẹ́ oko, tó fi hàn pé àlááfíà láwọn èèyàn Jèhófà á máa wá. Kí làwọn ohun èlò yìí nígbà ayé Aísáyà?

‘Wọn yóò fi idà rọ abẹ ohun ìtúlẹ̀’

1 Abẹ ohun ìtúlẹ̀ ni ohun èlò kan tí wọ́n fi máa ń wú ilẹ̀. Irin ni wọ́n fi máa ń ṣe àwọn kan.​—1Sa 13:20

‘Wọn yóò fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ọ̀bẹ ìrẹ́wọ́-ọ̀gbìn’

2 Irin ni wọ́n fi ń ṣe ọ̀bẹ ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn, ó máa ń rí kọrọdọ, ó sì mú. Ó máa ń ní ibi téèyàn ti lè dì í mú. Ohun èlò yìí wúlò gan-an fún rírẹ́ ọwọ́ àjàrà.​—Ais 18:5

ìdà àti ọ̀kọ̀
Abẹ ohun ìtúlẹ̀ àti ọbẹ̀ ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́