ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 2
  • December 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 2

December 5-11

AÍSÁYÀ 1-5

  • Orin 107 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Jẹ́ Kí A Gòkè Lọ sí Òkè Ńlá Jèhófà”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Aísáyà.]

    • Ais 2:2, 3​—“Òkè ńlá ilé Jèhófà” dúró fún ìjọsìn tòótọ́ (ip-1 ojú ìwé 38 sí 41 ìpínrọ̀ 6 sí 11 àti ojú ìwé 44 àti 45 ìpínrọ̀ 20 àti 21)

    • Ais 2:4​—Àwọn tó ń jọ́sìn Jèhófà kò kọ́ṣẹ́ ogun jíjà mọ́ (ip-1 ojú ìwé 46 àti 47 ìpínrọ̀ 24 àti 25)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 1:8, 9​—Ọ̀nà wo la ó gbà fi ọmọbìnrin Síónì “sílẹ̀ bí àtíbàbà inú ọgbà àjàrà”? (w06 12/1 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 5)

    • Ais 1:18​—Kí ni ìtúmọ̀ ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ pé: “Ẹ sì jẹ́ kí a mú àwọn ọ̀ràn tọ́ láàárín wa”? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 1; it-2-E ojú ìwé 761 ìpínrọ̀ 3)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 5:1-13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú láti kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 139

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (7 min.) Ẹ tún lè jíròrò ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 34 ìpínrọ̀ 1)

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Máa Lo Ìwé ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’ Láti Dénú Ọkàn Àwọn Èèyàn”: (8 min.) Ìjíròrò. Gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ní iṣẹ́ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lóṣù yìí níyànjú pé kí wọ́n fi ìmọ̀ràn tó wà lójú ìwé 261 àti 262 nínú ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́runsílò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 5 ìpínrọ̀ 1 sí 9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 154 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́