ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 4
  • December 12-18

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 12-18
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 4

December 12-18

AÍSÁYÀ 6-10

  • Orin 116 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Tó Ní Ìmúṣẹ ”: (10 min.)

    • Ais 9:1, 2​—Àsọtẹ́lẹ̀ ti wà nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ ní Gálílì (w11 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 13; ip-1 ojú ìwé 124 sí 126 ìpínrọ̀ 13 sí 17)

    • Ais 9:6​—Ó máa ní ọ̀pọ̀ ojúṣe lónírúurú láti bójú tó (w14 2/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 18; w07 5/15 ojú ìwé 6)

    • Ais 9:7​—Ìṣàkóso rẹ̀ máa mú àlááfíà àti ìdájọ́ òdodo wá fún aráyé (ip-1 ojú ìwé 132 ìpínrọ̀ 28 àti 29)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ais 7:3, 4​—Kí nìdí tí Jèhófà fi dáàbò bo Áhásì Ọba tó jẹ́ ẹni burúkú? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 4)

    • Ais 8:1-4​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ? (it-1-E ojú ìwé 1219; ip-1 ojú ìwé 111 àti 112 ìpínrọ̀ 23 àti 24)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 7:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.6 tó wà lójú ìwé 2

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.6

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 34 ìpínrọ̀ 18​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 10

  • “Èmi Nìyí! Rán Mi!” (Ais 6:8): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní A Kó Lọ Síbi Tí Wọ́n Ti Nílò Oníwàásù Púpọ̀ Sí I] .

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 5 ìpínrọ̀ 10 sí 17, àpótí “Ọkàn Ti Wá Balẹ̀ Dáadáa Wàyí”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 150 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́