ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 6
  • Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìwà ẹ̀tanú—ìṣòro tó kárí ayé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ìgbà Wo Ni Ayé Yìí Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀tanú?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ṣé O Ní Ìkórìíra?
    Jí!—2020
  • Ìgbà kan Ń Bọ̀ Tí Kò Ní Sí Ẹ̀tanú Mọ́
    Jí!—2004
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú

Jèhófà kì í ṣe ojúsàájú. (Iṣe 10:34, 35) Ó tẹ́wọ́ gba àwọn èèyàn “láti inú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ènìyàn àti ahọ́n.” (Iṣi 7:9) Torí náà, ìjọ Kristẹni kò fàyè gba ìwà ẹ̀tanú, a ò sì ń gbè sẹ́yìn ẹnì kankan. (Jak 2:1-4) Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ló jẹ́ kí èyí ṣeé ṣe, a sì ń gbádùn Párádísè tẹ̀mí èyí tó ń ràn wá lọ́wọ́ láti yí ìwà wa pa dà sí rere. (Ais 11:6-9) Bá a ṣe ń sapá láti fa ohunkóhun tó jẹ mọ́ ìwà ẹ̀tanú tu kúrò lọ́kàn wa, ńṣe là ń fi hàn pé a jẹ́ aláfarawé Ọlọ́run.​—Ef 5:1, 2.

Johny àti Gideon ń kí àwọn ọmọdé káàbọ̀ sí Gbọ̀ngàn Ìjọba

WO FÍDÍÒ NÁÀ JOHNY ÀTI GIDEON: Ọ̀TÁ NI WỌ́N TẸ́LẸ̀, WỌ́N TI DI ARÁKÙNRIN BÁYÌÍ. KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí nìdí tí ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fi ṣàǹfààní ju ìsapá àwọn èèyàn láti fòpin sí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà àti ẹ̀tanú?

  • Kí ló wú ẹ lórí nípa ẹ̀gbẹ́ ará wa tó kárí ayé?

  • Báwo la ṣe ń gbé Jèhófà ga tá a bá mú kí ìṣọ̀kan wà nínú ìjọ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́