October 22-28
JÒHÁNÙ 15-17
Orin 129 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé”: (10 min.)
Jo 15:19—Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù “kì í ṣe apá kan ayé” (“ayé” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 15:19, nwtsty)
Jo 15:21—Àwọn èèyàn kórìíra àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù nítorí orúkọ rẹ̀ (“ní tìtorí orúkọ mi” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 15:21, nwtsty)
Jo 16:33—Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù lè ṣẹ́gun ayé tí wọ́n bá tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù (it-1 516)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jo 17:21-23—Ọ̀nà wo ni àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù lè gbà jẹ́ “ọ̀kan”? (“ọ̀kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 17:21, nwtsty; “ṣe wọ́n pé ní ọ̀kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 17:23, nwtsty)
Jo 17:24—Kí ni “ìgbà pípilẹ̀ ayé”? (“ìgbà pípilẹ̀ ayé” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Joh 17:24, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 17:1-14
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 14 ¶3-4
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ìfẹ́ Ni A Fi Ń Dá Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Mọ̀—Yẹra fún Ohun Tó Lè Ba Ìṣọ̀kan Jẹ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà “Ẹ Ní Ìfẹ́ Láàárín Ara Yín”—Má Ṣe Máa Kọ Àkọsílẹ̀ Ìṣeniléṣe. Bí àkókò bá ṣe wà sí, sọ̀rọ̀ lórí àpótí náà “Ṣàṣàrò Lórí Àpẹẹrẹ Inú Bíbélì.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 14 ¶15-19, àpótí Báwo Ni Mo Ṣe Jẹ́ Olóòótọ́ Tó?
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 106 àti Àdúrà