ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 15-17
“Ẹ Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé”
Jésù ṣẹ́gun ayé nítorí pé kò fara wé ayé lọ́nàkọnà
Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù nílò ìgboyà kí wọ́n má bàa jẹ́ kí àwọn èèyàn tó wà nínú ayé yìí sọ wọ́n di bí wọ́n ṣe dà
Jésù ṣẹ́gun ayé, táwa náà bá ń ronú lórí àpẹẹrẹ tí Jésù fi lélẹ̀ fún wa, a máa ní ìgboyà tí àwa náà nílò láti lè ṣẹ́gun ayé