January 27–February 2
JẸ́NẸ́SÍSÌ 9-11
Orin 101 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Èdè Kan Ni Gbogbo Ayé Ń Sọ”: (10 min.)
Jẹ 11:1-4—Àwọn kan bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ìlú kàn àti ilé gogoro kan láti ta ko ìfẹ́ Ọlọ́run (it-1 239; it-2 202 ¶2)
Jẹ 11:6-8—Jèhófà da èdè wọn rú (it-2 202 ¶3)
Jẹ 11:9—Àwọn èèyàn náà pa iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe tì, wọ́n sì tú ká (it-2 472)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 9:20-22, 24, 25—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé Kénáánì ni Nóà gégùn-ún fún dípò Hámù? (it-1 1023 ¶4)
Jẹ 10:9, 10—Ọ̀nà wo ni Nímírọ́dù gbà jẹ́ “ọdẹ alágbára tó ń ta ko Jèhófà”? (it-2 503)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 10:6-32 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló fi hàn pé àwọn akéde yìí ti jọ múra ìpadàbẹ̀wò náà sílẹ̀? Báwo ni arákùnrin yẹn ṣe nasẹ̀ ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́, tó sì fi bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìpadàbẹ̀wò kejì, kó o sì lo ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà. (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Túbọ̀ Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Rẹ”: (15 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 15 ¶8-14
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 56 àti Àdúrà